EmmaOMG – E Ti Tobi to (Live) [feat. Pelumi Deborah, BBO & The OhEmGee Choir]

EmmaOMG – E Ti Tobi to (Live) [feat. Pelumi Deborah, BBO & The OhEmGee Choir]
E Ti Tobi to (Live)
EmmaOMG (feat. Pelumi Deborah, BBO & The OhEmGee Choir)
    Lyrics copied!
    E Ti Tobi to (Live) Album Art
    "E Ti Tobi to (Live)." - EmmaOMG (feat. Pelumi Deborah, BBO & The OhEmGee Choir)

    Album: E Ti Tobi to (Live) - Single
    Track No: 01

    Oluwa tobi ni Sioni
    O si j'oba lori orile-ede
    Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru
    pre-chorus
    E ni pe gbogbo aye n wariri
    Ni oruko re
    Won n k'orin
    E ti tobi to o
    Jesu
    Eh eh
    Eh eh (Make some noise)
    Eh eh
    Eh eh
    Eh eh
    Eh eh
    Eh eh
    Eh eh
    Eh eh
    Ani Oluwa tobi ni Sioni
    O si j'oba lori orile-ede
    Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru
    Shout hallelujah
    'Tori gbogbo aye n wariri
    Ni oruko re
    Won n k'orin
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon orun na n s'eleri
    Won n f'oribale
    Niwaju ite re o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Won ni E ti tobi to o
    Oooo
    Oluwa wa
    E ti tobi to o
    Jesu
    Won ni e ti tobi to ooo
    Oooo
    Ooo Oluwa wa o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Ani gbogbo aye n wariri o
    Ni oruko re
    Won n k'orin yeh
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon orun na n s'eleri
    Won n f'oribale
    Niwaju ite re o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Won ni E ti tobi to o eh
    Ooooo
    Oluwa wa o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Won ni e ti tobi to o
    Ooooo
    Ooo Oluwa wa o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon oke nla nla won f'oribale
    Tori Iwo ni ogo ati ola
    Ju oke nla ikogun won ni lo
    E ti tobi to o
    Jesu
    Iwo ti Olorun
    Ji dide kuro ninu oku
    Lati gba wa kuro
    Ninu ibinu ti'n bo o
    Eti tobi to o
    Jesu
    Iwo Oluwa Olorun
    To n gbe laarin awon Kerubu
    T'o po ni ipa ati agbara o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Ani gbogbo aye n wariri
    Ni oruko re
    Won n k'orin yeh
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon orun na n s'eleri
    Won n f'oribale
    Niwaju ite re o
    E ti tobi to o (Ladies and gentlemen)
    Jesu (Welcome Pelumi Deborah)
    Eeeeeeh
    E ti tobi to Jesu
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon orun n soro ogo Olorun
    Ofurufu n fi ise re han
    Ojo de ojo n f'ohun
    Oru de oru n fi imo han oooo
    E ti tobi to o
    Jesu Jesu oooo
    Jesu
    Ko si ibi kan tabi ede kan
    N'ibi ti a ko ti gbo iro wan
    Iro won la aye ja aaaaah
    E ti tobi to o (Jesu Jesu Jesu o)
    Jesu
    Mo le ko gbogbo eyin mi si Inu apere re
    Tori o to gb'ojule
    O to f'eyinti
    O to f'arati
    Olodumare
    E ti tobi to o
    Jesu
    Okun ri o o sa
    Jodani ri o o pada s'eyin
    Oke kekeke o je duro
    Niwaju Olodumare
    E ti tobi to o (Apata Idigbolu)
    Jesu (Apata Idigbolu)
    Apata ayeraye
    Ibi isadi mi
    Eni ti mo f'eyin ti
    Ti ko le wo
    Ti ko le si
    Ti ko le yi ni'po pada
    E ti tobi to o
    Jesu
    'Torina
    Gbogbo aye n wariri
    Ni oruko re
    Won n k'orin
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon orun na n s'eleri
    Won n f'oribale
    Niwaju ite re
    E ti tobi to o
    Jesu
    Won ni e ti tobi to o
    Oooo
    Oluwa wa
    E ti tobi to o
    Jesu
    Won ni e ti tobi to o
    Ooooo
    Oluwa wa
    E ti tobi to o
    Jesu
    Bibeli ni ti Oluwa ni ile ati ekun re
    Aiye, ati awon ti o tedo si Inu re
    Nitori ti o fi idi re sole lori okun
    O si gbeka awon isan-omi
    Tani yio gori oke Oluwa lo?
    Tabi tani yio duro nibi mimo re?
    Eniti o ni owo mimo ati aya funfun
    Eniti ko gbe okan re ka'le soke si asan
    Ti ko si bura etan
    Oun ni yio ri ibukun gba
    Ati ododo l'owo Olorun igbala re
    Eyi ni iran awon ti n se aferi re
    Ti n se aferi re Olorun Jakobu
    E gbe ori yin s'oke, eyin enu-ona
    Ki a si gbe'yin s'oke, eyin ilekun ayeraye
    Ki Oba ogo ki o wole wa
    Tani Oba ogo?
    Oluwa ti o le ti o l'agbara
    Oluwa ti o l'agbara ni ogun
    E gbe ori yin s'oke, eyin enu-ona
    Ki a si gbe'yin s'oke, eyin ilekun ayeraye
    Ki Oba ogo ki o wole wa
    Tani Oba ogo?
    Oluwa Olorun awon omo ogun
    Oun na ni Oba ogo (Jeeeesu)
    Ladies and Gentlemen
    Welcome Minister BBO
    Eni ti ite re ki si
    Eni ti ite re ki sa
    Oloruko ape-ri-iye
    Ar'aye-r'orun leekan soso
    E ti tobi to o
    Olorun majemu
    Jesu
    Araye n bo o
    Ara orun n bo o
    Apebo ni o
    Olodu Omo Are
    Oloruko ape ri iyanu
    E ti tobi to o (eeeeeeeeh)
    Jesu
    Iwo to koja riri tan
    See finish ko si l'oro re o
    Iranlowo eni ti o l'eyan
    Oba awon oba Olorun mi
    E ti tobi to o (yeeeeh)
    Jesu
    Olorun to n da ase pa
    Oo gba'se l'owo enikeni ko to p'ase
    Ta lo dabi ire ninu agbara
    Olorun majemu
    Eti tobi to o (Eeeehhh)
    Jesu
    Iwo to ma n tun ori alaisuwon se
    Pelu owo agbara
    O ro e l'orun
    Ko ni e l'ara
    Irorun lo ba de l'odo re Oko mi
    E ti tobi to o (Yeeeh)
    Jesu
    O da aye s'ori omi, omi o je gbe'le aye lo
    Tani o to ri e tan Olorun majemu
    Iranlowo eni ti o l'eyan, oko mi
    E ti tobi to o
    Asoisotan Olodumare
    Jesu
    Olorun ti o ki n rin irin idoti
    Olorun ta o le fi iwosi re l'ara
    Oluwa Oluwa wa o
    Olorun majemu, Olorun mi
    E ti tobi to o
    Jesu
    Ani gbogbo aye n wariri
    Ni oruko re
    Won n k'orin
    E ti tobi to o
    Jesu
    Awon orun na n s'eleri
    Won n f'oribale
    Niwaju ite re oooo
    E ti tobi to o
    Jesu
    hook
    Won ni pe
    Won ni pe
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba n gb'osuba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (E ba mi o)
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba n gb'osuba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (See see see)
    Let me teach you the Juba dance
    Eeeh
    Eeeh
    Eeeh
    Eeeh
    Eeeh
    Oya e ba mi o
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba n gb'osuba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (E ba mi e ba mi e ba mi)
    E ba mi juba f'ajunilo (E ba n gb'osuba)
    E ba n gb'osuba f'ajunilo (Awon agbagba)
    E ba mi juba f'ajunilo (merinlelogun won n ju'ba)
    Won n ju'ba (E maa ju'ba lo)
    E ba mi juba f'ajunilo (E ba wa ju'ba e ba mi ba mi o)
    E ba mi juba (Eh) f'ajunilo
    Oba to n be lori ite titilai (E ba n gb'osuba f'ajunilo)
    A da'ra po mo awon orun lati keee (E ba mi juba f'ajunilo)
    Mimo mimo mimo
    E ba mi juba f'ajunilo (Si Oluwa Olorun Olodumare)
    E ba mi juba f'ajunilo (A si ite wa le'le)
    A si aye wa le'le (E ba n gb'osuba f'ajunilo)
    A gbe s'ori ese re ooooo (E ba mi juba f'ajunilo)
    Jesu oooo
    E ba mi juba f'ajunilo
    BBO ju'ba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (E ju'ba f'olojukan)
    Ti n wo egbegberun eniyan (E ba n gb'osuba f'ajunilo)
    E ju'ba f'oloruko ape ri iye ooo (E ba mi juba f'ajunilo)
    E ba mi juba f'ajunilo (A ju'ba fun e Mogaji awon alagbara)
    E ba mi juba f'ajunilo (A ju'ba re oba to n so egan d'ogo)
    E ba n gb'osuba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (Eh eh eh eh eh eeeeeh)
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (Aju'nilo o)
    E ba n gb'osuba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo
    E ba mi juba f'ajunilo (tori pe)
    O wa pel'awon
    Ero mimo l'ona (O si je o)
    O si je
    Imole won
    L'osan l'oru
    Ani O wa pel'awon
    Ero mimo
    L'ona o
    O si je
    Imole won
    L'osan l'oru
    Gbogbo aye n wariri
    Ni oruko re
    Won n k'orin, (e ti tobi to o)
    E ti tobi to o
    Jesu
    Somebody shout Hallelujah
    Thank You jesus
    Thank You jesus
    Hallelujah
    Hallelujah
    Hallelujah
    Hallelujah thank You
    Thank you Jesus
    Awon orun na s'eleri
    Won n f'oribale
    Niwaju ite re o
    E ti tobi to o
    Jesu
    Thank You Jesus
    Hallelujah!

    Writer(s): EmmaOMG, Pelumi Deborah, BBO, The OhEmGee Choir.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    E Ti Tobi to (Live)

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!