Tope Alabi – E Gbe Ga Lyrics

Tope Alabi – E Gbe Ga Lyrics
E Gbe Ga
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    E Gbe Ga Album Art
    "E Gbe Ga." - Tope Alabi

    Album: Angeli Mi
    Track No: 05

    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    Oba to yi gbe aye mi pada
    Eba mi gbe ga
    Oun lo so ekun mi derin
    Eba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    Oba to yi gbe aye mi pada
    Eba mi gbe ga
    Oun lo so ekun mi derin
    Eba mi gbe ga oo
    Bi mo ji lowuro, ma gbe ga
    Owuro mi t'Oluwa ni
    Olugbe ori mi soke ni
    Losan ma yin Oluwa, ma gbe O ga
    O fun mi lonje oojo o, ki febi pa mi
    Toba dale ma yin o
    Tori oun lolusoaguntan mi
    Nigba kigba laye kaye
    Ma gbe o ga
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    Oba to yi gbe aye mi pada
    Eba mi gbe ga
    Oun lo so ekun mi derin
    Eba mi gbe ga oo
    Mo yin Oluwa oo, mo gbe o ga
    Oba to so mi deni giga
    To gbekun ose lenu mi
    O fibukun ore ko mi lona
    O fade wura de mi lo ri
    O gba mi lowo ota
    Gbi gbega Olorun mi
    Ore to se laye mi akaikatan, ma gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    Oba to yi gbe aye mi pada
    Eba mi gbe ga
    Oun lo so ekun mi derin
    Eba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga oo
    Oba to yi gbe aye mi pada
    Eba mi gbe ga
    Oun lo so ekun mi derin
    Eba mi gbe ga oo
    Arabata ribiti Olódùmarè
    Ọlọ́run àwọn ọlọ́run
    Ma gbe ga ma gbé ga o baba o se
    (Má gbé ga oo)
    Ìwọ lọ lọrun tí ó lafiwe
    Kò sí rú rẹ, láyè lọrun
    Má gbé ga má gbé ga ó bàbà ó ṣe
    (Magbe gaa ó)
    Èmi ó ní sàì gbé ọ ga
    Kò kuta ile, má gba ṣé mi ṣé
    Má gbé ga má gbé ga ó baba ó se
    (má gbé ga ó)
    Gbígbé ga ní o, ọba tó mọ yẹ irawo
    Má gbé ga má gbé ga ó bàbà ó ṣe
    Má gbé ga o
    Ọrẹ elese tó yí lè ayé mi pada
    To sọ mí dẹni ọtun
    Má gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
    Má gbé ga o
    Ìgbà mo ń bẹ láyé má yín ọ ó
    Ọlọ́run ayọ' mi ò
    Má gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
    Má gbé ga o
    Má yín ó títí Imi mi yóò fi pín
    A lo ju bẹ ẹ lọọ
    Má gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
    Má gbé ga o
    Ọba tó sọ ẹkùn mi derin
    Òun ló ní kín máà yoo
    Má gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
    Má gbé ga o
    Má gbé ga, Magbe ga, Magbe ga,
    Ọlọ́run ayo mi oo
    Má gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣe
    Má gbé ga o
    E ó, e o, ẹyin Olúwa
    E ó, e o, ẹyin Olúwa
    Gbógbó àgbáyé tí tí ayé, tí tí ayé
    Titi ayé é, má yín Olúwa
    Gigiga nínú, ọlá ńlá Ọlọ'run Ọba
    Tí tí ayé, má yín Olúwa
    Titi ayé, títí ayé
    Òpó mú lérò, ìwọ ni bàbá ẹ ṣé
    Titi ayé, títí ayé
    Titi ayé ẹ, má yín Olúwa
    Kabiyesi mo gbósu ba
    Ose ó bàbà
    Oba titi aye oo, ose o
    Ọlọ'run pípé ni o
    A lai labawon
    Oba titi aye oo, ose o
    Kari aye kari ola
    Ọba tó ń bẹ nibi gbogbo
    Oba titi aye oo, ose o
    A rí ro àlá, àdììtú Olódùmarè
    Oba titi aye oo, ose o
    Alágbára ńlá ń lá
    Omi tí ń mi le aye
    Oba titi aye oo, ose o
    A báni já, má je bí
    A ń ké pe nibi, ọrọ ó ń su wọn
    Oba titi aye oo, ose o
    Àìkú, aisa, aidibaje, Ọlọ́run ti kí ṣe ènìyàn
    Oba titi aye oo, ose o
    Oyigiyigi ọba tí kì sún, Kìí de tó rún gbe
    Oba titi aye oo, ose o
    Òkúta ìdí gbó lu ni o, Ilé ìṣo agbára mi
    Oba titi aye oo, ose o
    Chineke idinma Imela oo
    Oba titi aye oo, ose o
    Abasi so so o, Abasi amanamo
    Momiri maku abo o, wame e
    Oba titi aye oo, ose o
    Almasiu séríkí ngigi, nagode yesu
    Oba titi aye oo, ose o
    Asa agbara kiki da agbara
    Owo nla arogun má ti di ooo
    Oba ńláńlá ńlá
    To lo kanrin kese to lo kan rinnnnn
    keeeeeese

    Writer(s): Tope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    E Gbe Ga

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!