Barry Jhay – Ma So Pe Lyrics

Barry Jhay – Ma So Pe Lyrics
Ma So Pe
Barry Jhay
    Lyrics copied!
    Ma So Pe Album Art
    "Ma So Pe." - Barry Jhay

    Album: Barry Back
    Track No: 07

    Mo má dúpẹ' Bàbá ooo
    Elẹrú mí yín o (it's Bizzouch)
    Mo má dúpẹ', oo-eh
    Oii-nih
    Baba, I see
    I see the weather too coming through for me
    With Your power, I dey see front oo, eh-eh
    You do me wetin, nobody fit to do-do for me
    Oii-nih
    Oh-oh
    Orí adé ló ṣé mí oo, oh na-na
    Ṣé bí 'wo lónì ńmá j'ọba, eh-ee
    Orí mí tètè lá, k'orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o
    Ẹ'dá mí tètè lá, k'ẹ'dá ọlọ́lá máà pé ẹ o
    Mà ṣọ'pẹ
    F'ore tó ṣé láyé mí, òpọ púpọ', ye o
    Ọba ayérayé, ráyé
    Mà ṣọ'pẹ (ooh-)
    F'ore tó ṣé láyé mí o, opọ púpọ', ye o
    Ọba ayérayé, ráyé
    Say me, I don't know, know
    Say me, I no know, know
    Daddy, why You love me so? Walahi
    Why You love me so oo?
    I don't know, I no know
    Me, I no know o
    Why you love me so oh?
    Why you love me so oo? (Oii-nih)
    Bàbá Mímọ' o
    Orí adé ló ṣé mí oo, eh-eh-eh, ee
    Ṣébí 'wo lónì ńmá jọba
    Orí mí tètè lá, k'orí ọlọ́lá má pé ẹ rán níṣẹ̀ o
    K'ẹda mí tètè lá, k'ẹda ọlọ́lá má pé ẹ o
    Mà ṣọ'pẹ
    F'ore tó ṣé láyé mi, o pọ púpọ', ye oo
    Ọba ayérayé, ráyé
    Mà ṣọ'pẹ (ooh-)
    F'ore tó ṣé láyé mi o, o pọ púpọ', ye o
    Ọba ayérayé, ráyé, 'ayé
    (It's STG)

    Writer(s): Barry Jhay.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Ma So Pe

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!