"Clear." - Portable
(Ilu)
(Shoka lo ṣe beats)
Shoka lolu beat oh
Ika producer carry me trabaye o
Orin n bẹ niku mi, anjọnu olorin, Ọmọlalọmi Akerin o
Them call me Portable Baby oh
Turn up, shaku-shaku
Wọn sare lọ, unfollow wa o tori wọn ri jẹ lara wa mọ
Ko si yẹn mọ, ọmọ ologo ti gbera tan
Moya tete ya danu o, k′ọn to para pẹlu Jagamu o
K'ọn ma lọ ka mi mọ, mo ya tete sapa mọ o
Na mi get Zazu, are you mad on something o?
I′m a bigi man, ṣe mo jọ talaka o?
Ọmọlalọmi Akerin o, them call me Portable Baby o
Turn up, Shaku-shaku o, emi ni wèrè olorin o
If you no get money (clear)
Ko ya tete ya danu o (clear)
Olowo ni ṣ'ọrẹ olowo (clear)
Olowo la wọn ọrẹ mi (clear)
Isọkusọ mapa data (clear)
Ṣọ'ra fun awọn ripper (clear)
If you no get money, ko ya, ko ya danu o (clear)
Clear, clear, clear, clear, clear, clear
Clear
Emi Ika o, baba Ika o, eyan Ika o, wu wa Ika o
Ika o le wo oju ka o (clear)
Ika n bẹru ika o (clear)
Ika o le dẹmọ fun ika o (clear)
Ika ranju mọ ika o (clear)
Ọmọ oro mi, know person o (clear)
If you trust person o (clear)
You go learn lesson o (clear)
Ọmọ better, more blessing o, ma lọ dapọ mọ ero
Dapọ abi ko danu o
Ọrẹ star, star ni o, gbogbo nkan by lucky ni o
If you no get money (clear)
Ko ya tete ya danu o (clear)
Olowo ni ṣ′ọrẹ olowo (clear)
Olowo la wọn ọrẹ mi (clear)
Isọkusọ mapa data (clear)
Ṣọ′ra fun awọn ripper (clear)
If you no get money, ko ya, ko ya danu o (Ilu)
Clear, clear, clear, clear, clear, clear
If you no get money, ko ya, ko ya danu o (clear)
Wọn sare lọ, unfollow wa o tori wọn ri jẹ lara wa mọ
Ko si yẹn mọ, ọmọ ologo ti gbera tan
Moya tete ya danu o, k'ọn to para pẹlu Jagamu o
K′ọn ma lọ ka mi mọ, mo ya tete sapa mọ o
Na me get Zazu, are you mad on something o?
I'm a bigi man, ṣe mo jọ talaka o?
Ọmọlalọmi Akerin o, them call me Portable Baby o
Turn up, Shaku-shaku o, emi ni wèrè olorin o (Ilu)
Writer(s): Portable.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Clear