Tope Alabi – Tipa Tikuuku Lyrics

Tope Alabi – Tipa Tikuuku Lyrics
Tipa Tikuuku
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Tipa Tikuuku Album Art
    "Tipa Tikuuku." - Tope Alabi

    Album: Oruko Tuntun
    Track No: 09

    Tipa tikuuku
    Oluwa mu mi lo shey rere
    Tipa tikuuku
    Oluwa mu mi lo shey rere
    Boya mofe
    Boya mo ko
    Oluwa mumi de'be
    Tipa tiku (tipa tikuuku, oluwa mu mi lo shey rere)
    Mu mi lo shey rere (tipa tikuuku) tipa tiku (oluwa mu mi lo shey rere)
    Boya mo fe (boya mo fe, boya mo ko o, oluwa mu mi de'be)
    verse
    Omo Israeli lojo yen oo
    Tipa tikuuku na fi de'le Ileri
    Obediedomu gba kamu
    Opelope apoti eri
    Josefu iba ma tayo
    Biwon o ba ta leru lojo yen
    Oluwa lai fi temi shey
    Jowo mu mi de'bi ogo
    chorus
    Ma fi temi shey (tipa tikuuku) aha (oluwa mu mi lo shey rere)
    Oluwa ma woju mi rarara (tipa tikuuku) tipa tikuuku (oluwa mu mi lo shey rere)
    Mu mi lo (boya mo fe, boya mo ko, oluwa mu mi de'be)
    verse
    Omo o ni inakuna ojosi
    T'ero e ti pin
    O pada r'oju rere baba
    Mefiboseti aro ni
    O pada wa d'eni toun b'oba Jeun
    Lairotele Maria gba ijise angeli
    O bi olugbala
    Olorun lai f'okan si mi
    Womi de'bi ayo mi
    chorus
    Jesu (tipa tikuuku)
    To ba ti fi was shey (oluwa mu mi lo shey rere)
    A oni kuro loju kan (tipa tikuuku) olurun wo was (oluwa mu mi lo shey rere)
    Lo shey rere e (boya mo fe, boya mo ko) boya a ko (oluwa mu mi de'be)
    verse
    Oluwa ma fi ti ogun idile shey
    Oluwa ma wo ojo ota ibi ishe mi
    Oluwa ma fi da do mi se
    Oruko to o pe mi je omo mi lori
    Iwo ni oloko ti o nwo oko aiye mi
    Po mi oluwa de'le ileri
    Ko je tipa tikuuku
    Jowo fa mi de bi ogo
    chorus
    Ata ye ro o (tipa tikuuku) emi ma be be olorun o (oluwa mu mi lo shey rere)
    Ma wo to ago mi (tipa tikuuku) Eni go lo po wun mo o (oluwa mu mi lo shey rere)
    Iwo ni a fi temi shey (boya mode, boya moko) Ma fami lo (oluwa mu mi de'be)
    (Tipa tikuuku) ni tipa ni tiku
    (Oluwa mu mi lo shey rere) kini o ba loro wun lele
    (Tipa tikuuku) olorun
    (Oluwa mu mi lo shey rere)
    Fun aye mi (boya mofe, boya mo ko)
    Boya mo fe (oluwa mu mi de'be)
    Amin (tipa tikuuku)
    Tipa tiku (oluwa mu mi lo shey rere)
    Pariwo ki oluwa mu e lo shey rere (tipa tikuuku)
    Ah eh (oluwa mu mi lo shey rere)
    Boya oluwa lo shey rere ni (oluwa mu mi lo shey rere)
    O ti pe a ti was lojuno (oluwa mu mi lo shey rere)

    Writer(s): Patricia Temitope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Tipa Tikuuku

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!