"Ashe She." - Barry Jhay
Tori mo mọ
Tori mo mọ
Tori mo mọ wipe a ṣe ṣe
Oh-oh, ti n ba ji l'owurọ, mo ma n gbadura
K'ori mi gbere ko mi, o-o-o-o-o-o, e
Unto say, I know say
Tori mo mọ wipe a ṣe ṣe
Oh, na-na
B'ọta gbogun, b'ọn binu o
Ooh-yeah, mo mọ p'Ọlọrun n bẹ lẹyin mi, oh-ooh
And anything wey I lay my hands on
Mo ni, "Mo mọ wipe a ṣe ṣe"
L'ọla Oluwa, ari bo ṣe fẹ, ọrẹ
Gbogbo nnkan temi, tirẹ a ṣe ṣe, ay
Bo ba n gbadura, e go be
O ni tẹ, o ni tii
Gbogbo nnkan laiye t'awa a ṣe ṣe
Ooh, yeah
Brother, ṣe you know, say prayer be the master key
If you no get God o, believe me, you no gat nothing (ah, ah-ah, yeah)
Eni to ba debẹ lo le sọ, ṣe o (ah, ah-ah, yeah)
Ẹni to ba mọ ṣa lo le ṣalaye o
But if you gat Him, He gat you, ṣo mọ? Oh-oh
If you call Him, He go answer, ṣo gbọ? Oh
Hold on to Him, He never let go, oh-ooh, oh-ooh, oh
He's gonna let the light in you show, oh-oh
B'ọta gbogun, b'ọn binu o
Ooh-yeah, mo mọ p'Ọlọrun n bẹ lẹyin mi, oh-ooh
And anything wey I lay my hands on
Mo ni, "Mo mọ wipe a ṣe ṣe"
L'ọla Oluwa, ari bo ṣe fẹ, ọrẹ
Gbogbo nnkan temi, tirẹ a ṣe ṣe, ay
Bo ba n gbadura, e go be
O ni tẹ, o ni tii
Gbogbo nnkan laiye t'awa a ṣe ṣe
So you do good do you do bad o
Ọmọ araiye no wan know, them must to talk, oh-oh, oh, oh
Anything wey you dey do, my brother, better do good o
'Cause na wetin go pay you-ooh
B'emi ba f'ọwọkan iṣẹti aṣọ rẹ o
Ara mi yi o ya-ah ga-ga, ah, ay
B'emi ba f'ọwọkan iṣẹti aṣọ rẹ-ooh
Ara mi yi o ya ga-ga, ga-ga, oh-ooh-ooh, yeah
B'ọta gbogun, b'ọn binu o
Ooh-yeah, mo mọ p'Ọlọrun n bẹ lẹyin mi, oh-ooh
And anything wey I lay my hands on
Mo ni, "Mo mọ wipe a ṣe ṣe"
L'ọla Oluwa, ari bo ṣe fẹ, ọrẹ
Gbogbo nnkan temi, tirẹ a ṣe ṣe, ay
Bo ba n gbadura, e go be
O ni tẹ, o ni tii
Gbogbo nnkan laiye t'awa a ṣe ṣe
Writer(s): Barry Jhay.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Ashe She