K1 De Ultimate – Awade Lyrics

K1 De Ultimate – Awade Lyrics
Awade
K1 De Ultimate
    Lyrics copied!
    Awade Album Art
    "Awade." - K1 De Ultimate

    Album: Fuji the Sound
    Track No: 01

    K1 de ultimate
    Fuji the sound
    Olorun lo fi ran emi Ayinde o
    God sent
    Iya ati baba won bi mi da
    Emi gangan mo tun tun ara bi
    Loruko oun se n ga si
    Iya ati baba won bi mi da
    Emi gangan mo tun tun ara bi
    Loruko oun se n ga si
    Omo gidi sa lo ye ka ya
    Ka si tun je ari koserere
    Ni tori awon ewe ni ojo iwaju
    Boy se rere boy o se re oooo
    Ba siko ba to Oluaye fuji mi
    Boy a ma ba aye ti e lo
    Ere sun si waju ko ti igba kankan duro o
    Eyan to ba ba oko yi daju la o jo
    Gun le si ebute ayo o
    Emi lo ni fujimi
    Tori onilu oni fe o tu
    Igba kan lo igba kan bo
    Ojo n gun ori ojo
    Gbogbo igba ki gba to ba de
    Layi eledumare je ko ba wa lara mu
    Eku ati ijo
    Se daada ni
    Eku ati ijo
    Laada ni
    Se alafia le
    Wa
    Gbogbo ile nko o
    Eku ati ijo
    E daada ni
    Eku ati ijo
    Daada ni
    Se alafía le wa
    T'aya tomo nko o
    Lse to se omo fun ogun odun
    Ya to je omo fun osu mefa o
    Bi o ba pa omo
    A si leyin omo ni
    Me le ni kan se o
    Me le ni kan se o
    Me le nikan se ile aye o0o
    Me le ni Kan se ile aye
    Ta da dan ta da
    Pa ra ra pam pam
    Pam pa ra
    Ton ton ton ton
    To to
    Me le ni kan se ile aye
    No one than God
    There is a moment in ones life time
    You've got to make an impression right on time
    Behold I have set the land before you go in
    And possess the land which the lord swear unto your fathers
    Abraham, Issac and Jacob
    To give unto them and to their seed after them
    The Lord your God hath multiplied you
    And behold Ye are this day as the stars of heaven
    For multitude
    Deuteronomy chapter 1 verse 1 to 10
    Awade n dededede de Awade
    Awa la n ko omo lede awade
    Awade n dededede de Awade
    Ayinde la n ko omo lede awade
    Omo eni o se idi bebere
    Akanke ade mi Melissa
    Ka fi ileke si idi omo elo mi
    Ayinde wasiu teni n teni teni n teni
    Ba n da kasa fomo Anifowose
    Na ehn
    Ban da kasa fomo Anifowose
    Ehn a enn
    Ban da kasa kasa kasa kasa kasa fomo
    Anifowose
    Ehn a ehn
    Me le sa yi jo fuji
    Tori alujo nbe ni be
    (Me le sa i jo Fuji)
    Me le sa yi jo fuji o
    Me le sa yi jo fuji o
    Tori alujo po pupo ni be
    Me le sayi jo Fuji

    Writer(s): Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Awade

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!