Barry Jhay – BLOOD OF THE LAMB Lyrics

Barry Jhay – BLOOD OF THE LAMB Lyrics
BLOOD OF THE LAMB
Barry Jhay
    Lyrics copied!
    BLOOD OF THE LAMB Album Art
    "BLOOD OF THE LAMB." - Barry Jhay

    Album: Barrystar Vol. 1 (Deluxe)
    Track No: 01

    (V-V-V-V Sticks)

    Ijẹtá, ′ṣèni mò kun lẹ, mòfẹ bá Ọlọhun s'ọrọ, miò mọ òhun ti mò fẹ sọ (miò mọ òhun ti mò fẹ sọ)
    Bimò ṣè n ri mu, má jẹn mu bọ, Èlèduwá (Èlèduwá)
    Ṣá má ṣọmi lọ (Ṣá má ṣọmi lọ)
    Baba, one grace yẹn ni, that one transaction
    E go change my life for good, oh (e go change my life for good)
    Igbágbọ mi sober wọ into gbògàn, òlèku

    Ápátá, dákálèlè tilè ò lè wò, Ẹ ṣá l′ágbárá
    T'òbá di gbè-gbè gbè, You steady come through for me
    Áyè ò fẹ ká r'ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash (fẹ ká r′ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, palash)
    Òhun t′ọmọ èniyàn ò mọ lò pọr ju
    B'Ọbá mi bá dè, á dábi wọ l′òmọ ṣèju ('mọ ṣèju)

    Ayy, Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy
    Iyin át′ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ'rọ
    Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy-ah
    Iyin át′ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ'rọ

    Ṣèbi iwọ l'ápáṣẹ, t′òn p′áṣẹ
    L'òri iṣẹ mi, p′áṣẹ ọtun
    N'ilè áyè mi, p′áṣẹ árá ò
    Inu ilè mi, p'áṣẹ ò
    Ṣèbi mò gb′òju lè, ayy
    Ṣèbi mò gb'ọkàn mi lè Ọ
    Ki Baba mi f'iyá gbọ òrukọ, áti kọ ọrọ rẹ, titi lái (titi lái)

    Ápátá, dákálèlè tilè ò lè wò, Ẹ ṣá l′ágbárá
    T′òbá di gbè-gbè gbè, You steady come through for me
    Áyè ò fẹ ká r'ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, yè (fẹ ká r′ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, palash, yè)
    Òhun t'ọmọ èniyàn ò mọ lò pọr ju
    B′Ọbá mi bá dè, á dábi wọ l'òmọ ṣèju (′mọ ṣèju)

    Ayy, Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy
    Iyin át'ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ'rọ
    Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy-ah
    Iyin át′ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ′rọ

    (Sunshine)

    Writer(s): Barry Jhay.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    BLOOD OF THE LAMB

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!