"Ààrẹ." - Brymo
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò-pàò
Ọlọpá wá o, ó máa gba rìbá
Òrékelẹwà jẹ a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ọlọpá wá o, ó máa gba rìbá
Òrékelẹwà, jẹ a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ẹku owurọ o (ọlọpá wá o)
Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí
Wọn ní, "Ní òwúrọ yìí, àwọn ọmọ éèès!
Wọn ti jà wọ'gboro
Wọn dẹ ti ń dáná sun'lé
Wọn tun dáná s'oko
Àt'ọkọ ayọkẹlẹ àti èyí tí ò yọkẹlẹ
Gbogbo ẹ lo dáná sun"
Ẹ gbélé yín o
Ẹ ṣọ'ra yín o
Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọdọ
Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó
Kí Ọlọrun kí ó máa ṣọ gbogbo wa o
Láyọ o, ẹ ṣe e
Ààrẹ ń bọ l'ájò
Àwọn ọ mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
Àwọn ọjẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ òfurufú
Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k'ore
Ààrẹ ń bọ l'ájò
Àwọn ọ mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
Àwọn ọjẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ òfurufú
Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k'ore
Writer(s): Olawale Olofo'ro.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Ààrẹ