Tope Alabi – Mimo L'Oluwa (Medley) Lyrics

Tope Alabi – Mimo L'Oluwa (Medley) Lyrics
Mimo L'Oluwa (Medley)
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Mimo L'Oluwa (Medley) Album Art
    "Mimo L'Oluwa (Medley)." - Tope Alabi

    Album: Angeli Mi
    Track No: 02

    Mimo l'Oluwa o (mimo)
    Angeli nwo mike o (mimo)
    Awon orun nwo mike (mimo)
    Egbagbeje irawo o (mimo)
    Mimo l'Oluwa (mimo)
    Angeli nwo mike o (mimo)
    Awon orun nwo mike (mimo)
    Egbagbeje irawo o (mimo)
    Agbagba merinlelogun (mimo)
    N'origun merin aye o (mimo)
    Ati oke, ati ile (mimo)
    Seri nwo ke o (mimo)
    Tani yo gori oke Oluwa (mimo)
    Tabi tani yo duro ni'be o (mimo)
    Eni ti o ni owo mimo (mimo)
    Ati aya funfun (mimo)
    Mimo l'Oluwa (mimo)
    Mimo o mimo (mimo)
    Mimo o mimo o mimo (mimo)
    Mimo o funfun nene ni (mimo)
    Kabiyesi Eledumare Oba mimo (mimo)
    Oba la gbogbo aye ete riba fun oba ti oda gbogbo adarihunhun
    Oba ti oni emi inu eniyan pata
    Oni kokoro aye l' lowo
    Adagodo emi gbogbo eniyan
    Olu kogan orun ajosi edumare
    Ibinigbi awuwo bi atele
    Opa tiri kole o ko orun
    Minimi ojo ti jeki ara odehin
    Orun wawa ti o pada bo si po
    Olorun ti o 'so osupa di ale ti oun t' oru
    Oba ti ose ohun gbogbo ni asiko ni asiko
    Oba ti ole fi eni 'yi ti, ti a ole fi eyi re ti laila
    Are la Oba ti eni kan obi, ti obi omo kari gbogbo aye koropodo
    Olowo ori gbogbo aye pata pata ni
    Oniwa funfun Oba dake se un ti enikan ole se un si
    Inu ogo gangan ni oti fo owu
    Ol' ogo ti oju ogo lo ni
    Ki abi o ko si
    Emi o je fi o sere
    Afi eni ti o ba fe gba query l'odore
    Mi oje fi oju di o
    Oba ti ose wo lo ju wo
    Oti e leti
    Aledibaje ni o
    Baba la kun Baba mi
    Ole gbi yeke
    Gbogbo eni ti oba mo riri Oluwa
    Ete riba ewa riri fun Oba nki shi
    Ibere ati opin Olorun ajanakun ti mi igbo kiji kiji kiji
    Ti abubu ti a le buto to posi ni gbogbo ojo
    Eje ka sapa fun Oba rere ti aba mo riri
    Emi inu awon woli mimo
    A tobi tan alainiye ko koja kika
    Terere ko ja riri to
    Gigun l' alopi
    Ailetunwo, adawunro, adawunso, adawunse
    Olulu awon orun, oke la ari owu masiti

    Writer(s): Tope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Mimo L'Oluwa (Medley)

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!