Tope Alabi – Omo Ranti Lyrics

Tope Alabi – Omo Ranti Lyrics
Omo Ranti
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Omo Ranti Album Art
    "Omo Ranti." - Tope Alabi

    Album: Agbelebu
    Track No: 06

    Omo Ranti o
    Omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse
    Igbala ni eee asiko imo re tide o
    Omo magbagbe eleda re
    Omo ranti
    Omo ranti ooo omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse
    Igbala ni eee asiko imo re tide o
    Omo magbagbe eleda re
    Magbgbe eni ti seda re
    Ile ti a fi tomo ire ni owo o
    Omo ti o la farada yoo san eje fatunbotan
    Igba lodo hun ni laye
    Agba fere kan odo na o
    Tara sasa omo lopin re koda
    Sekia nigba owuro omo Ranti o
    Omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse
    Igbala ni eee asiko imo re tide o
    Omo magbagbe eleda re
    Tanba ba owo wi to ba n warunki
    Awon agba lomo ta oko agbele tako ta o
    Sasa lomo ta oko o iwon lomo ton gboran o
    Omo ma pami to ba se die yoo domo mapara re
    Oti to jubo lo se yan eyi ofeyan yoya
    Booba ranti
    Oniba lo so bai loruko
    Oun to ba perare
    Opo omo ti bayelo won ti kasa idakuda
    Okunrin o le dobale kagba debi obinrin akunle ki enitoju
    Oro alufansa lenu won
    Awon omo nibi niran
    Aye n baje ema sope on dara
    Ogede n baje ema sope on pon
    Suuru baba iwa o kiise todo iwo yi mo o
    Odo aye ti towo bobo kubo afaitan bene ten mami bi erin lokun
    Omo ti o janu lenu omu to wa n femi famu owo o fe di borokinii lawujo
    Moto atata ile alara goolu iyebiye lo fera o
    Ema gbagbe aje iweyin to pelede ijosi iku ojiji dede lo fiyin sere
    Ma femi e toro fun satani jowo ronu o omo ranti omo ma gbagbe eleda re
    Be o ba gboro obi o te o tun gbo tolorun
    Dede iku n be lode iku ma n be lode on polowo eya
    Daakun egbooro mi keya gbotebi yungba yungba ayiyin ni
    Ke ma pa obi yin lekun me ma sowon
    Dagan ale yungba yungba ewu o ba nilara
    O ni le jakara ore ko tun mu dani
    Esin to sare irun ni orun gbeyin
    Ole ririn ajo kotun wa nile o ko ma lo jepe ko ma lo kuku
    Wa keni koto keji dandan ni Aikawe
    Aigbeko ofeyege elere egele alera efe
    Won fe gba okunkun dalagbara koni le lora emi rerara Ayobe a kun ebi
    Alapata o fe jere re sorun apadi ni ranti eleda re nigva ewe re jesu
    Feran re nigbati ojo ibi ko tii de
    Ogo olorun lo je mamaje kesu o yoo subu
    Fogo olorun han lana gbogbo
    Maje kohun aye tan o pa ojare
    Ki lelere eleda re ton pe o
    Omo pada ba eleda re laja
    To ba le yii pada ko satunse aye re
    Egbegbe yoo gba ye re lagbala
    Ma wobi okunkun to ti worin jina pada o le gba o se kia
    Edegbede yoo roo o lagbala
    Ojo iwaju re yoo ma da
    Ma beru eni Olorun le pa
    Eni to tooni gba ni o sa waba
    Edegbede yoo roo lagbala
    Eto to fisile fun o ju wura iyebiye lo
    Jesu duro lenu ona on duro on pe o o omo wole wole wole

    Writer(s): Patricia Temitope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Omo Ranti

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!