"EGBAMI." - Rexxie & Rybeena
(Yo)
Ọmọ Iya 'Dewale
(Big Vibes)
Ẹgbámi ẹgbámi, ẹgbámi (gbámi)
Iyawo ilè nfá Backii (Backii)
Ọkọ òku ni Gaji
Áni gbègun èlègun, ẹ ṣ'amin (ṣ'amin)
Ṣ'amin oh, ṣ'amin (ṣ'amin)
Black person no fit born áfin
Paddie mi, just one transaction, o lè rá'lè si Paris
Ẹgbámi, kilọmọ ájá nṣhèè niwáju predator?
Tinu bá bámi, molè ṣh'omọ inu elevator
Favor, Rexxie lo sọh fun mi "kin má calm down"
Molè ṣh'ọmọ to wun mi, as long t'obá ti standout
T'èmi báti l'òwò, dákun, k'iku má ṣh'ojoro
Ṣhibi to rọọbi 'ni ghetto l'ojẹ k'ọmọ kòbò (kòbò)
Nigga to gb'òwò mi jápá, òri ẹ yọ koko
Jẹjẹ ni Dodo min 'Dawa, all man no dey cap
My baby, my baby, I get my own for body
I no fit do me, can't no fuck up
My baby, no vex for me
My baby, my baby, I get my own for body
I no fit do me, can't no fuck up
My baby, no vex for me
Ẹgbámi ẹgbámi, ẹgbámi (gbámi)
Iyawo ilè nfá Backii (Backii)
Ọkọ òku ni Gaji
Áni gbègun èlègun, ẹ ṣ'amin (ṣ'amin)
Ṣ'amin oh, ṣ'amin (ṣ'amin)
Black person no fit born áfin
Paddie mi, just one transaction, o lè rá'lè si Paris
(Yo)
Ẹgbámi, kilọmọ ájá nṣhèè niwáju predator?
Tinu bá bámi, molè ṣh'omọ inu elevator
Favor, Rexxie lo sọh fun mi "kin má calm down"
Molè ṣh'ọmọ to wun mi, as long t'obá ti standout
(T'èmi báti l'òwò, dákun, k'iku má ṣh'ojoro), 'joro
(Ṣhibi to rọọbi 'ni ghetto l'ojẹ k'ọmọ kòbò), kòbò
(Nigga to gb'òwò mi jápá, òri ẹ yọ koko)
Jẹjẹ ni Dodo min 'Dawa, all man no dey cap
(Boombah)
Writer(s): Rexxie, Rybeena.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
EGBAMI