Brymo – Bá’núsọ Lyrics

Brymo – Bá’núsọ Lyrics
Bá’núsọ
Brymo
    Lyrics copied!
    Bá’núsọ Album Art
    "Bá’núsọ." - Brymo

    Album: Oṣó
    Track No: 11

    Abéré á lo
    Abéré á lo
    K′ó nà okùn ó tó dí ò
    A ò ní dé bá won
    A ò ní dé bá won
    Ení bá ní a máà de ò
    Bá'núso
    Bá′núso
    Má b'enìyan só
    Bá'núso
    Bá′núso
    Má b′enìyan só
    Omijé á gbe
    Omijé á gbe
    Ìbànújé á dèrin ò
    Eniafé
    Eniafé lamò o
    A ò mo'ni tó fé ni ò
    Bá′núso
    Bá'núso
    Má b′enìyan só
    Bá'núso
    Bá′núso
    Má b'enìyan só
    Ení bá ma b'ésù jeun
    Síbíi rè á gùn gan
    Eni ò mò áù
    Ówá jeé
    Òsèlú mà ló layé ò
    Bá′núso
    Bá′núso
    Má b'enìyan só
    Bá′núso
    Bá'núso
    Má b′enìyan só
    Èyin ará
    Ewá gbó òò
    Òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii
    Sé kín só
    Kín só
    Ká bá'núso
    Bá′núso
    N'òní b'enìyan só
    Bá′núso
    Bá′núso
    Má b'enìyan só
    Bá′núso
    Bá'núso
    Má b′enìyan só

    Writer(s): Olawale Olofo'ro.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Bá’núsọ

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!