Tope Alabi – Oluwa Otobi Lyrics

Tope Alabi – Oluwa Otobi Lyrics
Oluwa Otobi
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Oluwa Otobi Album Art
    "Oluwa Otobi." - Tope Alabi

    Album: Alagbara
    Track No: 01

    Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
    Ko s'eni t'a le fi s'afiwe Re o, O tobi
    Ko s'eda t'a le fi s'akawe Re o, O tobi
    Oluwa
    Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
    Ko s'eni t'a le fi s'afiwe Re o, O tobi
    Ko s'eda t'a le fi s'akawe Re o, O tobi
    Oluwa
    O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
    Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
    Pupopupo ni O, O koja omi okun at'osa, O ga po
    Ajulo O o se julo
    Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
    Ko s'eni t'a le fi s'afiwe Re o, O tobi
    Ko s'eda t'a le fi s'akawe Re o, O tobi
    Oluwa
    Oba lori aye, O tobi o eh
    Agba'ni loko eru, Olominira to n de'ni lorun
    O fi titobi gba mi lowo ogun t'apa obi mi o ka
    Olugbeja mi to ba mi r'ogun lai mu mi lo t'o segun
    Akoni ni O o
    Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
    Ko s'eni t'a le fi s'afiwe Re o, O tobi
    Ko s'eda t'a le fi s'akawe Re o, O tobi
    Oluwa
    B'O ti tobi to oo, laanu Re tobi
    B'O ti tobi se o, ododo Re tobi o
    O tobi tife tife, Oni majemu ti kii ye
    Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan
    Ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
    Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
    Ko s'eni t'a le fi s'afiwe Re o, O tobi
    Ko s'eda t'a le fi s'akawe Re o, O tobi
    Oluwa
    Akoko O tobi, O tobi o
    Oluwa
    Ipilese ogborin o yeye
    O tobi
    Ibere Eni to f'ogbon da ohun gbogbo
    Oluwa
    Igbeyin ola nla, o la la oo
    O tobi
    Opin aye a'torun ko si 'ru Re
    Oluwa
    O tobi, O o se s'akawe lailai o
    O tobi
    Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi
    Oluwa
    Awon angeli won n ki O, O tobi
    O tobi
    Olorun Elijah Ireti Ajanaku
    Oluwa
    O ma tobi laye mi, O tobi ooo
    O tobi
    Iwo lo gb'orin t'O o ga, t'O gun, t'O tun fe
    Oluwa
    O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la
    O tobi

    Writer(s): Patricia Temitope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Oluwa Otobi

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!