Sola Allyson – Eji Òwúrọ̀ 20 Lyrics

Sola Allyson – Eji Òwúrọ̀ 20 Lyrics
Eji Òwúrọ̀ 20
Sola Allyson
    Lyrics copied!
    Eji Òwúrọ̀ 20 Album Art
    "Eji Òwúrọ̀ 20." - Sola Allyson

    Album: Ìṣọ̀ṣọ́
    Track No: 01

    Duro ti mi o, Ololufe
    Ife ti ko labukun ni ko ba mi lo
    Duro ti mi o, Ololufe
    Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo
    Ife bi eji owuro
    Latagbala eledumare lo ti se wa
    Ife to toro minimini
    Ti abawon aiye kan, o le baje o
    Ololufe feran mi, lai se itan o
    Ife bi eji owuro
    Latagbala eledumare lo ti se wa
    Ife to toro minimini
    Ti abawon aiye kan, o le baje o
    Ololufe feran mi, lai se itan o
    Fe mi bi oju ti fe imu
    Fe mi bi irun ti fe ori
    Fe mi bi eyin ti fe nu
    Fe mi temi temi
    Fe mi tokantokan
    Fe mi tara tara
    Ololufe feran mi lai se itan o
    Fe mi bi oju ti fe imu
    Fe mi bi irun ti fe ori
    Fe mi bi eyin ti fe nu
    Fe mi temi temi
    Fe mi tokantokan
    Fe mi tara tara
    Ololufe feran mi lai se itan o
    Ife bi eji owuro
    Latagbala eledumare lo ti se wa
    Ife to toro minimini
    Ti abawon aiye kan, o le baje o
    Ololufe feran mi, lai se itan o
    Ba mi se otito, mo fe o toto
    Ba mi se ododo, mo fe o pelu ododo
    Ba mi se otito, mo fe o toto
    Ba mi se ododo, mo fe o pelu ododo
    Bo ogiri o ba lanu, alangba o le wo ogiri
    Bo ogiri o ba lanu, alangba o le wo ogiri
    Eleda lo yan wa papo, esu o ni ya wa o
    Ife bi eji owuro
    Latagbala eledumare lo ti se wa
    Ife to toro minimini
    Ti abawon aiye kan, o le baje o
    Ololufe feran mi, lai se itan o
    Ama lowo lowo
    Ama bimo le mo
    Ama se ayo mo ayo
    Ama se ola mo ola
    Ka sha mu ife eledumare se lai se itan
    Ama lowo lowo
    Ama bimo le mo
    Ama se ayo mo ayo
    Ama se ola mo ola
    Ka sha mu ife eledumare se lai se itan
    Ife bi eji owuro
    Latagbala eledumare lo ti se wa
    Ife to toro minimini
    Ti abawon aiye kan, o le baje o
    Ololufe feran mi, lai se itan o
    Gba imoran mi, Ololufe mi
    Oluranlowo la fi mi se fun o, lati orun wa
    Fe ti si omoran mi, Ololufe mi
    Oluranlowo la fi mi se fun o, lati orun wa
    Ka jo rin, ka shogo fun Oruko Olorun
    Alabarin la fi mi she fun o, lati orun wa
    Mo kan kuro ninu esan aiye, etan o da nkankan fun ni
    Ife ati ope lo le mu alaiye je lai labawon
    Mo kan kuro ninu esan aiye, etan o da nkankan fun ni
    Ife ati ope lo le mu alaiye je lai labawon
    Ife bi eji owuro
    Latagbala eledumare lo ti se wa
    Ife to toro minimini

    Writer(s): Olusola Allyson-obaniyi, Wole Adesanya.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Eji Òwúrọ̀ 20

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!