Aṣa – Grateful Lyrics

Aṣa – Grateful Lyrics
Grateful
Aṣa
    Lyrics copied!
    Grateful Album Art
    "Grateful." - Aṣa

    Album: Bed of Stone
    Track No: 06

    [Verse 1]
    Era ile, era ile, wọn yin baba l'oke
    Yanrin okun, yanrin okun, wọn yin baba l'oke
    Ẹranko ilé, ẹranko igbo wọn yin baba l'oke
    Àwọn aláìní, àwọn tan ti ni, wọn yin baba l'oke

    [Chorus]
    Kò se igbati nkan ba se yan, kò to mo pe baba n be l'oke
    Kò se igbati nkan ba se yan, kò to mo pe lóòtọ́ o n be l'oke
    You don't have to wait till you feel the pain, you can start right now
    It's not too late
    It's not too late, to be grateful

    [Verse 2]
    Era ile, era ile, wọn yin baba l'oke
    Yanrin okun, yanrin okun, wọn yin baba l'oke
    Pe mo wa l'ayé, mo wa l'aye
    Gbọgbọ òun ti mo ni, ma fin yin o l'ogo
    To live this world a better place

    [Chorus]
    Kò se igbati nkan ba se yan, kò to mo pe baba n be l'oke (Okay)
    Kò se igbati nkan ba se yan, kò to mo pe lóòtọ́ o n be l'oke
    You don't have to wait till you feel the pain, you can start right now (Okay)
    It's not too late
    It's not too late, to be grateful (Yeah)

    [Outro]
    Wo mi, bi mo ṣe n f'egbe yín baba
    [Non-lyrical vocals]
    It's not too late
    [Non-lyrical vocals]
    (Yeah, yeah)

    Writer(s): Aṣa.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Grateful

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!