"Dewale." - Rybeena & King Dr. Saheed Osupa
('Dewale)
(Ọmọ Iya 'Dewale)
('Dewale)
(Ọmọ Iya 'Dewale)
(Coz-Coz-Cozmicaudio)
('Dewale)
(Ọmọ Iya 'Dewale)
('Dewale)
(Japh Kenti)
(Ọmọ Iya 'Dewale)
Hmm, uhm-yeah
Salam alaykum, walaykum salam, mò k'ònilè (walaykum salam, mò k'ònilè)
Álárẹmu òlòrin, t'àjò dè ní Bonsue
Ọmọ ẹgbá l'èmi, miò lè f'òsi ọwọ juwè
Ilè baba mi, Atanda ọmọ Ṣubuládè
Mama mi á má sọ fun mi, pè "ò ṣi má dá" (ò ṣi má dá)
Wọn ni pè "inu jin, kin sọrá f'ònilárá" (f'ònilárá)
Mò sọkò s'ọjá, árá lò f'árápá
Ánfáni pọn nbẹ gidi t'òbá ṣè dádá-ah
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ádun má dè)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ádun má dè)
Kọ kin mu late cormer ni'lè áyè ò (uh-mm)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ay-uhn)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ọrẹ mi, ádun má dè ò)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ọrẹ mi, ádun má dè ò)
Kọ kin mu late cormer ni'lè áyè ò
Ọrẹ mi, ádun má dè ò
Ayy, mò gbọ pè ayy, mò gbọ pè
Mò gbọ pè ẹtin gbá nkàn ribiti tin j'òkò nlá
Aunty Abbey, ni'lè ákọku, ṣ'ẹn ráyè
Ṣ'ẹti gbàgbé pè ájá tò wọ'lè t'ẹkun, ṣè ẹ mọ'pè iku l'òun wá
Mò gbọ pè ayy, mò gbọ pè
Mò gbọ pè ẹtin gbá nkàn ribiti tin j'òkò nlá
Aunty Abbey, ni'lè ákọku, ṣ'ẹn ráyè
Ṣ'ẹti gbàgbé pè ájá tò wọ'lè t'ẹkun, ṣè ẹ mọ'pè iku l'òun wá
Áyè támọtiyè, mò bẹru áyè, mò s'áfun áyè (áyè)
Òju ti r'òkun, r'ọsá, ẹ bèèrè mi l'ọwọ 'Motunde (l'ọwọ 'Motunde)
Áyè támọtiyè, mò bẹru áyè, mò s'áfun áyè (áyè)
Òju ti r'òkun, r'ọsá, bèèrè mi l'ọwọ 'Motunde
Òkun áti igbá t'ẹju si kọngá, tẹ gbò'ju
Ẹsò, òmi l'òlọlè bu wá k'òju tò mọ
Áb'ẹlẹjá yàn, ku iṣẹ ò, èmi mò l'ẹjá mi
B'ẹjá jinà, á di t'ẹlẹjá ò, ẹlẹjá yin á jẹ òju
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ádun má dè)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ádun má dè)
Kọ kin mu late cormer ni'lè áyè ò (uh-mm)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ay-uhn)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ọrẹ mi, ádun má dè ò)
Ọrẹ mi, ádun má dè ò (ọrẹ mi, ádun má dè ò)
Kọ kin mu late cormer ni'lè áyè ò
Ọrẹ mi, ádun má dè ò
(Thank you for your peaceful cooperation)
(Japh Kenti, Japh Kenti)
Writer(s): Rybeena, King Dr. Saheed Osupa.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Dewale