"Olorun." - Asake
Ololade mi Aşakę
Emi kọ, Olọrun ma ni
Awa kọ, ọ ọ
Emi kọ o
Olọrun ma ni
Ta lo gbọn t'Olorun? (Ọmọ ọgbọn)
Ko si anybody t'o l'ogbon t'Olorun
Ti wọn ba buga ẹ o, ya gba fun Olorun
Awọn ti wọn buga mi, wọn ti sa pamọ
Wọn ti sa pamọ
Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Ọlọrun ma ni o)
Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Olorun ma ni o)
Awa kọ, ọ, Ọlọrun ma ni o (Oh oh oh)
Emi kọ o, Olọrun ma ni o
Ọmọ no be me, şebi na God
Carry me from down straight to the top
2020 was real-tough
Fall for ground, almost gave up (Gave up)
Mo fun won l'Omọ Ope mo dę ję lo o
Go naked in my room, I speak to God
Baba God, I no sabi all
So guide me, as I dey move on on on on
Ta lo gbọn t'Olorun?
Ti wọn ba buga ẹ o, ya gba fun Olorun
Awọn ti wọn buga mi, wọn ti sa pamọ
Nkan kan o gbọdọ ş'ọmọ ologo
Nkan o gbọdọ mi ọmọ ọlọrun o
Alhamdulillah I’m a brand new man
Tune in to the King of Sounds and Blues
Writer(s): Ahmed Ololade.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Olorun