"Olúmọ." - Brymo
Mo nlọ s′Ake, mo fẹ' lọ rọ′jọ'gbọ'n o
Mo nlo s′Abeokuta, mo fe lọ ri
Omo Soyínka
Osoyinka
Osoyinka
Osoyinka
Be lọ s′Owu
Be ba r'Aremu o
Be ba ri Baba Iyabo, ẹ ba mi ki
Ẹbọra Owu
Ẹbọra Owu oo
Ẹbọra Owu, eeh
Ẹbọra Owu oo
Be lọ s′Abeokuta, ìlo Olúmọ
Bẹ ba r'Alake, ẹ ba mi ki
Writer(s): Olawale Olofo'ro.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Olúmọ