"Adé Orí Òkin." - K1 De Ultimate
Ayinde Ogun
Bí ẹ̀yàn bá ń yọ ilé dá
Òun búburú a máa yọ irú wọ́n ṣe ní
Mo ti sọ tèlè tèlè
Nínú orin tó rìí kọjá
Ení Ọlọ́run fẹ́ lọ ọmọ ẹ̀yàn fẹ́
Ẹ máa yọ̀nú sí mi
Àgbà àti ọmọ dé
Ẹ máa yọ̀nú sí mi o
Ọkùnrin t'óbìnrin
Ẹ yọ̀nú sí mi
Eni báa ń yọ̀nú sí mi
Ṣùgbọ́n
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Òun lè ó máa rí
Mo ní ẹ máa yọ̀nú sí mi
Ọkùnrin ẹ yọ̀nú sí mi
Obìnrin ẹ yọ̀nú sí mi
Gbogbo ení báa ń yọ̀nú sí mi o
Ṣùgbọ́n
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Ìyọ̀nú Ọlọ́run Ọba
Òun lè ó máa rí
Àánú mo rí gbà
Adé orí okin
Àánú mo rí gbà
Adé orí okin
Èmi ń jáyè orí mi
Adé orí okin
Kí de ṣe mímọ́ ṣe
Adé orí okin
Kí máa de ṣe mímọ́ ṣe
Adé orí okin
Àánú mo rí gbà
Adé orí okin
Ọmọ aládé àlàáfíà
Adé orí okin
Ayinde, ọmọ aládé àlàáfíà
Adé orí okin
Irán ẹyà kìnìún Júdà
Adé orí okin
Gbóǹgbó ìdí ilé Jésè
Adé orí okin
Àánú mo rí gbà
Adé orí okin
Ọlọ́run ló gbé ọ̀gọ́ fún ọ̀lẹ
Adé orí okin
Ọlọ́run ló gbé ọ̀gọ́ fún ọ̀lẹ
Adé orí okin
Kì í ṣe fún ẹyẹ k'ẹyẹ
Adé orí okin
Kí máa dé ṣe fún ẹyẹ k'ẹyẹ
Adé orí okin
Ọmọ Sikiru Ayinde Barrister
Adé orí okin
Sikiru Ayinde mo ń jẹ́ ìṣe tó rán mí o
Adé orí okin
Lórí eré fújì
Adé orí okin
Kò dì í bàjẹ́ Ọlọ́run
Adé orí okin
Mo dúpẹ́ orí mi
Adé orí okin
Mo máa dúpẹ́ orí mi
Adé orí okin
Writer(s): Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Adé Orí Òkin