"Ìpín." - Sola Allyson
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN O
BEFORE I WAS FORMED IN MY
MOTHER'S WOMB
BẸ'Ẹ'NI
BEFORE I WAS FORMED IN MY
MOTHER'S WOMB
MO TI YÀN'YÍ O
ÌPÍN MI RÈÉ O MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' ÒUN NÌKAN NI
ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN ELÉDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN ELÉDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN ELÉDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÈMI Ò TÌẸ' MỌ' MO KÀN Ń R'ÌRÌN
MI LỌ NI ÈMI Ò MỌ'
MI Ò MỌ' B'Ó ṢE JẸ'
OJÚ U MI L'Ó LÀ TÍ MO FI MỌ'
ÌPÍN NÁÀ RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
BEFORE I WAS FORMED NÍNÚ ÌYÁ À MI
L'A TI YÀN MÍ O
ÈMI NÁÀ RÈÉ O
ÒGO NI MÀÁ ṢE FÚN ỌBA T'Ó NI ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ A TI YÀN MI
MI Ò MỌ' P'Ó MÁA LE B'Ó ṢE LE Ń'GBÀ YẸN
ṢÙGBỌ'N MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌDÀÀMÚ LÈ WÀ L'Ọ'NÀ ÌBÀNÚJẸ'
LE WÀ L'Ọ'NÀ ṢÙGBỌ'N MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
L'ÈLÉTÒ ÌPÍN Ó TI DÁ MI PẸ'LÚ ÌPÍN MI
ÌPÍN RÈÉ O MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ÀÁNÚ WÀ, ÌRÀNWỌ' WÀ
ÀÁNÚ WÀ LÁTI ÒKÈ
LÁTI ÀGBÀLÁ ÌMỌ'LẸ'
ÌPÍN RÈÉ O MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' TÈMI
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ÌMỌ'LẸ' TÈMI KÒ JỌ T'ẸLÒMÍÌ
Ọ'DỌ' ONÍÌMỌ'LẸ' ṢÁÀ NÁÀ L'Ó TI WÁ
ÌMỌ'LẸ' TÈMI OLÚṢỌLÁ ÀṢÀKẸ'
ARẸ'SẸ'TẸLẸ
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O
ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O
ÌMỌ'LẸ'. YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
KÍ ÀWỌN T'Ó BÍ MI
K'Ọ'N TÓ PÀDÉ ARA WỌN RÁRÁ
A TI YÀN MÍ O
PÉ ỌMỌ ÌMỌ'LẸ' L'ÈMI
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ N'ÌPÌLẸ' AYÉ
A TI YÀN'PÌN O
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
OHUN TÍ MO BÁ Ń'LẸ' Ó MÚ ÌDÀÀMÚ WÀ
ÌPÍN MI NI
SÍBÈ ÀÁNÚ WÀ
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN O
AYÉ Ń MO DÉ L'Ọ'NÀ Á WỌ'
ÀÁNÚ WÀ SÍBẸ'
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN O
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O
ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O
ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
MÀÁ FI Ṣ'Ẹ'WÀ
MÀÁ FI Ṣ'ỌLÁ
S'Ọ'BA ÒKÈ T'Ó L'ỌLÁ
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
N'ÌPÌN TI DÚÓ
ỌJỌ' Í B'Ẹ'BẸ' ÀTI YỌ
ÌMỌ'LẸ' Í B'Ẹ'BẸ' ÀTI TÀN
ÌṢẸ'DÁ ÌMỌ'LẸ' L'ÈMI
MI Ò NÍ B'Ẹ'BẸ' ÀTI HÀN
ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ỌJỌ' Í B'Ẹ'BẸ' ÀTI YỌ
ÌMỌ'LẸ' Í B'Ẹ'BẸ' ÀTI TÀN
ÌṢẸ'DÁ ÌMỌ'LẸ' L'ÈMI
MI Ò NÍ B'Ẹ'BẸ' ÀTI HÀN
ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
YOU MUST WORK
YOU MUST WATCH
WATCH AND PRAY
WORK AND PRAY
Ọ'RỌ' NI O
Ọ'RỌ' ÌMỌ'LẸ' NI
YOU WILL WATCH AND PRAY
YOU WILL WORK AND PRAY
WÀÁ Ṣ'IṢẸ' T' Ó YẸ K'ÓO ṢE
WÀÁ RÌNNÀ T'Ó YẸ K'ÓO RÌN
PROCESS, STEP UPON STEP
L'A MÀÁ FI DÉ'BẸ' YẸN
BẸ'Ẹ'NI, ỌMỌ MÁ GBÀGBÉ O
IṢẸ' WÀ T'ÁA MÀÁ ṢE
IṢẸ' WÀ T'ÁA MÀÁ ṢE
ṢÙGBỌ'N SÍBẸ' ÌMỌ'LẸ' YẸN
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
I HAVE MADE UP MIND
WHATEVER COMES ON MY WAY
MÀÁ TÀN'MỌ'LẸ' MÀÁ TÀN'MỌ'LẸ'
AYÉ Á RÍ MI WỌ'N Á RÍ ÌMỌ'LẸ' OLÓGO
THAT THE OWNER OF TOMORROW
Ó NÍ ÌFẸ' SÍ MI
ÌFẸ' RERE L'Ó NI SÍ MI
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
IT HAD BEEN PLANNED THAT
I WILL BE LIKE THIS
ṢÙGBỌ'N MÀÁ RÌN MÀÁ RÌN
L'Ọ'NÀ ÌMỌ'LẸ'
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
Ó N'ÍBI TÍ ÌMÍSÍ TI Ń WÁ FÚN MI
ÌFẸ' IBẸ' NI MÀÁ ṢE
ÌMÍSÍ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
O N'ÍBI TI ÌMÍSÍ TI MÀÁ NWA FÚN MI
ÌMÍSÍ YẸN MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
IBI ÌMỌ'LẸ' N'ÌMÍSÍ MI TI Ń WÁ
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ'LẸ' T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ'RUN OLÓDÙMARÈ
ONÍÌMỌ'LẸ' O ÌMỌ'LẸ' YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ
ỌLỌ'RUN ÌMỌ'LẸ'
ÌRAN YÍ LÁT'ORÍ I TÈMI YO MA
ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ'RUN OGO
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ, MI
Ò R'ÍRÚ Ẹ' RÍ ṢÙGBÓN Á T'ORÍ MI BẸ'RẸ'
ỌLỌ'RUN ÌMỌ'LẸ'
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ N'ÍKỌ'KỌ' NÍ
GBANGBA O, ỌLỌ'RUN OGO
ÌRAN YÍ YÓÒ MÀÁ Ṣ' ÀFẸ'RÍ RẸ
ỌLỌ'RUN ÌMỌ'LẸ'
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ
ỌLỌ'RUN ÒGO
ÌRAN MI YÓÒ MÁA Ṣ'ÀFẸ'RÍ Ẹ
KÒ ṢẸLẸ' RÍ NI MO GBỌ'
ṢÙGBỌ́N Á T'ORÍ Ì MI BẸ'RẸ'
IRAN MI YÓÒ MÀÁ WÀ NÍNÚ ÌFẸ' RẸ
ỌLỌ'RUN ÒGO
ỌLỌ'RUN ÌMỌ'LẸ' T'Ó
JÓÒKÓ S'ÓRÍ ÒBÍRÍ AYÉ
MÀÁ ṢÈ'FẸ' Ẹ' RẸ
Writer(s): Sola Allyson.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Ìpín