Tope Alabi – Funmilayo Lyrics

Tope Alabi – Funmilayo Lyrics
Funmilayo
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Funmilayo Album Art
    "Funmilayo." - Tope Alabi

    Album: Agbara Olorun
    Track No: 01

    Olorun lo le fun ni layo
    Eniyan ole funi layo kope
    Bo pe titi oo akololo a pe baba
    Oba oke lo layo pupo lodo
    Funmilayo
    Funmilayo
    Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
    Olorun lo le fun ni layo
    Eniyan ole funi layo kope
    Bo pe titi oo akololo a pe baba
    Oba oke lo layo pupo lodo
    Funmilayo
    Funmilayo
    Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
    Bi emi basi wa laye ireti o pin oo
    Atoro ohun gbogbo lowo olorun ki kan ju o
    Oro olorun ko ni lo laiye se laye
    Bi omo kiniun wonma kigbe ebi kikan
    Awon to gbekele ki yo shale yi ri ohun ti o dara
    Olorun lo le fun ni layo
    Eniyan ole funi layo kope
    Bo pe titi oo akololo a pe baba
    Oba oke lo layo pupo lodo
    Funmilayo
    Funmilayo
    Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
    Bi igba ban gba ni ejiki ama ro ju
    Igba nbo ti o gba ni olorun lo ni dede
    Ironu o da nkan
    Ore lo ni suuru
    Eti olorun ko wu wo lati gbo igbe wa
    Igba gbo ninu Jesu lo le mu ni se ase yege
    Olorun lo le fun ni layo
    Eniyan ole funi layo kope
    Bo pe titi oo akololo a pe baba
    Oba oke lo layo pupo lodo
    Funmilayo
    Funmilayo
    Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
    Gbe okan le jesu apata ti kin ye
    Matori a ro pin ko se si eleda re
    Pada leyin aiye ni se ni won to ni pa
    Aiye a funi ni fila a fi gba odindin ori eni l'owo eni
    Won ti mi a si regun ko ni wu won de ti gbe san
    Olorun lo le fun ni layo
    Eniyan ole funi layo kope
    Bo pe titi oo akololo a pe baba
    Oba oke lo layo pupo lodo
    Funmilayo
    Funmilayo
    Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
    Ori to mi a da de ko ma ni se a i de
    Funnnnnmilayo
    Baba fun mi layo ma je ki temi o gbe oo
    Funnnnnmilayo
    Ohun to ye mi o baba ma fi dunmi o baba rere amin
    Funnnnnmilayo
    Oro ti mo ba araye wi to ya gere ba mi se baba
    Funnnnnmilayo
    Mo mope omo to mi a gun eseee re a tirin
    Funnnnnmilayo
    Gbogbo a sise jeje eleri e je kalo mu suuru
    A fe re bo na
    Funnnnnmilayo
    T'ori koko to mi a j'ata idi re a koko gbona, uh uh uh
    Funnnnnmilayo
    E je ka se fun olorun loke loke l'owo a fun ni gbe eyen je oto
    Funnnnnmilayo
    Ohun ti afe gba l'owo olorun oju ohun ti a le fun lo eh eh
    Funnnnnmilayo
    Eni ba fe jeun gboingboin ati eleku gboingboin, tooto niyen
    Funnnnnmilayo

    Writer(s): Patricia Temitope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Funmilayo

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!