Tope Alabi – Oba Aseda Lyrics

Tope Alabi – Oba Aseda Lyrics
Oba Aseda
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Oba Aseda Album Art
    "Oba Aseda." - Tope Alabi

    Album: Oruko Tuntun
    Track No: 01

    A toto n to Olodumare, Olorun ogo,
    Iba Re, Iba o, Akoda aye, Iwo nikan lo to, iba!
    A de'da, a m'eda Oba
    Alamo to mo 'ponri eda o
    Akoko orun on aye
    Opo kan a gbamu aye o
    Ogo ni mo wa yin o o Oba
    Kabiyesi Re, Olorun toto
    Ogo, yeeee, ogo
    Akoko ade Iwo loba
    Omimi aye ti o le mi lailai o
    Olu inu awon orun
    Asaya apesin asako
    Iwo to tobi ju o lorun
    O f'aye s'apoti itise lasan
    Ogo, yeeee, ogo
    Ogo ye o, yeeeee ogo
    Olorun agbaye, mo f'ogo fun O ooo
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Iwo lajulo ti o see julo, mo f'ogo fun O Baba
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Atetekose Adiitu Oro, mo f'ogo fun O Baba
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Alapanla to so'le aye ro, mo f'ogo fun O ooo
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Iwo ni 'gunwa ogo ti o lafiwe, mo f'ogo fun O Oba nla
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Awari Re aimo ni f'aye at'orun
    Ipa o to ju gbogbo ipa lo
    Angeli o le s'akawe ogo Re
    Didan ninu ewa at'orun d'orun
    O da'ye k'ohunkohun to d'aye
    Akoko k'angeli orun to wa
    Iwo to n s'ohun to tobi ju awari lo
    Owo ogo to f'ara s'ohun gbogbo logo
    Ogo yeeeee ogo
    Iba o, yeeeee iba o
    Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e
    Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si
    Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o
    Olorun agbaye, mo f'ogo fun O ooo
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Erujeje Arugbo Ojo, Agba lailai on lo je
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Olurapada wa, Ododo to n tan 'mole
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Oba t'aa bi, sugbon ti a ko da
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Ilekun to ti mo iku, Kokoro si iye ayeraye
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    You are the Might above all mights
    Angels count Your glory, incomparable
    Shining in beauty from heaven to heaven, Creator of eternal things
    You are the first, before the heavenly angels
    You bigger than searchable
    Glorious and stylishly working all glory
    Glory Oh Glory (Ogo ogo)
    Unquestionable Great King, be Thou glorified Daddy
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Awon angeli juba Re, lojoojo o lorun
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Embodiment of wisdom and power You are
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Agbaagba lorun juba Re, won fi'ba yi O ka Baba
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Worker of numerous wonders, worshipped in trembling
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Gbogbo aye mi ni mo fi juba Re, gba ogo lori mi o Baba
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    You are the King Creator, be Thou glorified
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Ola ododo lo to si 'Wo nikan nikan o
    Iwo loba Aseda, mo f'ogo fun O
    Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e
    Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si
    Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o

    Writer(s): Patricia Temitope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Oba Aseda

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!