Tope Alabi – Fimi Dara Ire Lyrics

Tope Alabi – Fimi Dara Ire Lyrics
Fimi Dara Ire
Tope Alabi
    Lyrics copied!
    Fimi Dara Ire Album Art
    "Fimi Dara Ire." - Tope Alabi

    Album: Alagbara
    Track No: 05

    Olorun ara
    S'aye mi ni re
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun ara
    Oni'nu are
    Fimi dara to wunmi ooo
    Olorun Ara
    S'aye mi logo
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun Ara
    Oni'nu Ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Oba tomomi
    Tonimi, todami ooo
    Alara oni sababi
    Wa S'aye mi nire
    Mo fowo mi gba'rimi mu oo
    Sanu Ori mi
    Mo fowo mi gba'rimi mu oo
    Wa sanu ori mi
    Olorun ara
    S'aye mi ni re
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun ara
    Oni'nu ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Olorun ara
    S'aye mi logo
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun Ara
    Oni'nu Ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Iwo lo da da daa
    To da ohun gbogbo saye
    Odani to momi ooo
    Kima waye wa jiya
    Edu'a Olohun gbogbo lowo
    Seke mi o Baba
    Akan ii kere ainile Lori
    Aja ikere ee gbigbo
    Ologbo ii kere a n leku paje
    Maje n kere si're owo re
    Kin se rere laye
    Kima seru egbe mi o
    Kima waye wa woran
    Kint'egbe mi o
    Kin tun jogba lo
    Waa 'bukun f'emi ooo
    Olorun ara
    S'aye mi ni re
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun ara
    Oni'nu ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Olorun ara
    S'aye mi logo
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun ara
    Oni'nu ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Oba Alara, Oni'nu ara
    Babara Ara n be lowo re
    Eni to ku O ku Lofi dara ti o to oo
    Wafimi da repete ara nla
    Awimayehun oo
    Eleberu Ike, Fimi dara to wunmi oo
    Mikili ko o ku ofi dara ti o daa oo
    Nebuchadnezari gberaga
    Ofi dara ti o wun oo
    Olorun ara
    S'aye mi ni re
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun ara
    Oni'nu ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Olorun ara
    S'aye mi logo
    Fimi dara to da Baba oo
    Olorun Ara
    Oni'nu ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    S'anu aye mi o Baba
    Eni to ba fi dara ire
    Kii fara sinu ku
    Jekara ayemi kowu egbe mi o
    Alara topo, Onike ara
    Fi mi dara to wu aye mi
    Apesin ola, Oba nla
    Adagagede onilekun ore
    Apela oloro to po
    Onire Jan ran abani mayo
    Wa fa ye mi dara ire
    Olorun ara
    Oni inu ara
    Fimi dara to wunmi ooo
    Agbalagba oro
    Oni bu Ola
    Kiki da ara ni ofi da orun
    Ara nla to da aye
    Opolopo oro
    Ingbala Ola la
    Aje ori oro
    Ileke Ibikun
    Oni opa ara
    Olorun akoda ola
    Ijinle oro to ga, ga, ga
    Alara to po o
    Ma fi mi da ara ti ko da
    Baba alara ire
    Wa fi mi dara ire
    Wa fi mi dara ire
    Wa fi mi dara ire
    Wa fi mi dara ire
    Wa fi mi dara ire
    Wa fi mi dara ire

    Writer(s): Patricia Temitope Alabi.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Fimi Dara Ire

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!