"Ayonbo." - Barry Jhay
Oh-oh, eh, ah-eh
O rí pé, ayọ ń bọ l′òwúrọ, eh-eh
(Ice)
Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọ ń bọ l′òwúrọ
T'obà r'ọwọ Oluwa nílé àyé rẹ
Ṣa tí mọ wípé, ayọ ń bọ l′òwúrọ, ye o
Ayọ ń bọ wa l′òwúrọ oo, eh
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ, eh
Ẹkùn le pẹ títì d′alẹ, ṣùgbọn, ayọ ń bọ l'òwúrọ
I say, "Joy in the morning"
Joy every day, that′s all I see
Oh, eh-eh, Baba God, na Your light dey shine on me like this o
I no know how to thank You, uh-yea, yea-yea
Every day, burst my brain every day, make me want me to dey pray
Na you be my God, yea, Baba oh-ye
Na You dey bless the person wey no get, Bàbá naa ni
Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọ ń bọ l′òwúrọ
T'obà r'ọwọ Oluwa nílé àyé rẹ
Ṣa tí mọ wípé, ayọ ń bọ l′òwúrọ, ye o
Ayọ ń bọ wa l′òwúrọ oo, eh (mo ni, "ayọ, ayọ, ayọ")
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ, eh
Ẹkùn le pẹ títì d′alẹ, ṣùgbọn, ayọ ń bọ l'òwúrọ
Hmm, na You be the God promise
Na You be the God of Covenant o
The promise wey You do for my life o, má jẹ ko kọjá mí
Na You, na You o, na only You o
Ìwọ ṣa lo ń ṣọ mi o, iwọ ṣa lo ń ṣe òun gbogbo eh
Burst my brain every day (every day), make me want to dey pray
Na you be my God, yea, Baba oh-ye
Na You dey bless the person wey no get, Baba naa ni
Mo r′ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọ ń bọ l'òwúrọ
T′obà r'ọwọ Oluwa nílé àyé rẹ
Ṣa tí mọ wípé, ayọ ń bọ l'òwúrọ, ye o
Ayọ ń bọ wa l′òwúrọ oo, eh (mo ni, "ayọ, ayọ, ayọ")
Ayọ ń bọ wa l′òwúrọ, eh
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọn, ayọ ń bọ l′òwúrọ
Eh-eh-eh-eh, uh-oh (Ice)
Ayọ ń bọ l'òwúrọ
Yea-yea-yea-oh-uh-oh-oh
Ice, ayọ ń bọ l′òwúrọ
Writer(s): Barry Jhay.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Ayonbo