"Ire." - Sula & Barry Jhay
(Vxtis)
Oh-oh-oh
Emi ni Barry, Barry t′ọn ko jẹ
Ṣebi, iwọ to ṣ'ana o
Bo mu eni ṣe ni
Mo ṣe n gbẹsẹ l′ẹkọọkan
To mi s'ọna ire
To ba wa d'ọla ma le pada dupẹ, oh-eh
Yeah, iwọ to ni mi, to l′ẹmi mi
Iro yii to lebọ mi
When enemy say them go put fire for my ṣòkòtò
You fight for me o
You fight
Oh-oh, You fight for me
Odoju t′ọta
O p'ọta lẹnu mọ, ẹ ṣeun
Oh, ta ni ma pe ti wahala bá dé?
Ìwọ naa ni
Ìwọ naa ni, oh-oh-oh
Since I was born, and now I am getting old
I have never seen my Lord change
Oh, no-no
Iwọ lo ṣ′ana o
Bo mu eni ṣe ni
Bi mo ṣe n gbẹsẹ l'ẹkọọkan
To mi s′ọnà ire
To ba wa d'ọla ma le pada dupẹ, oh-eh
Yeah, iwọ to ni mi, to l′ẹmi mi
Ìwọ nikan lo le gba mi la lọjọ-kọjọ
Iwọ nikan lo le tun temi ṣe o
Ko ma s'ẹni naa to le gba'po rẹ laye mi oh
Akaka′tan niṣẹ rẹ o eh, e-yeah, e-yeah
Ta ni ma pe ti wahala ba dé?
Ìwọ naa ni
Iwọ naa ni, oh-oh-oh
Since I was born and now I am getting old
I have never seen my Lord change
Oh, no-no
Iwọ lo ṣ′ana o
Bo mu eni ṣe ni
Bi mo ṣe n gbẹsẹ l'ẹkọọkan
To mi s′ọnà ire
To ba wa d'ọla ma le pada dupẹ, oh-eh
Yeah, iwọ to ni mi, to l′ẹmi mi (yeah)
Writer(s): Oluwakayode Junior Balogun.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Ire