Barry Jhay – Bless Me Lyrics

Barry Jhay – Bless Me Lyrics
Bless Me
Barry Jhay
    Lyrics copied!
    Bless Me Album Art
    "Bless Me." - Barry Jhay

    Album: Son of God
    Track No: 07

    Yeah-yeah, ah-ahh, ah
    Ṣijú àánú wo mí oh, Elédùmarè, Bàbá
    Oh-ahh-ayy, ah-ayy
    Ayy, na-na (Ice) (ayy, na-na, na, na, na)

    T′ọmọdé, t'àgbàlagbà, lo ńw′ojú réré rẹ
    Ukwu-ukwu ku, wọn w'ojú réré rẹ
    Ẹni tó l'owo àt′ẹni o ní, wọn w′ojú réré rẹ
    Kos'òun t′ole ṣe, kos'òun to pọju fún o láti ṣe

    Ìwọ ṣa l′Ọba, kos'Ọba mí rán lẹ′yìn rẹ, lẹ'yìn rẹ o
    Kos'ẹlòmíràn, Bàbá bless me, yeah-oh
    Bàbá, jọwọ, bless me (eh, ah-ah)
    Olú Ọrùn, níbo l′ojú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
    À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
    Olu Ọrùn, yeah, níbo l′ojú rẹ wà? Ayy o
    À fẹ reeti rẹ oh
    Olu Ọrun, níbo l'ojú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
    À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
    Olu Ọrùn, yeah, níbo l′ojú rẹ wà? Ayy o
    À fẹ reeti rẹ, oh

    Ìwọ lo s'ọkọ fún opó
    Ìwọ ní Bàbá ′láì ní bàbá, ayy, oh-ah
    Ìwọ ní má pé tí wàhálà bá dé
    Kos'ẹlòmíràn, àfi ìwọ, oh-oh
    Àfi iwọ, májẹ k′ojú tí mí

    T'ọmọdé, t'àgbàlagbà lo ńw′ojú réré rẹ
    Ukwu-ukwu, ku, wọn w′ojú réré rẹ
    Ẹni tó l'owo àt′ẹni o ní, wọ́n w'ojú réré rẹ
    Kos′òun t'ole ṣe, kos′òun tó pọ'ju fún o làti ṣe

    Ìwọ ṣa l'Ọba, kos′Ọba mí rán lẹ′yìn rẹ, lẹ'yìn rẹ o
    Kos′ẹlòmíràn, Bàbá bless me, yeah-oh (níbo l'ójú rẹ wa? Yeah)
    Bàbá, jọwọ, bless me (eh, ah-ah)
    Olú Ọrùn, níbo l′ójú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
    À fẹ reeti rẹ o, Bàbá
    Olú Ọrùn, yeah, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy o
    À fẹ reeti rẹ o
    Olú Ọrùn, níbo l′ojú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
    À fẹ reeti rẹ o, Bàbá
    Olú Ọrùn, yeah, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy o
    À fẹ reeti rẹ o

    Ẹni o l'ójú, ó fún l′ójú k′ofi rí rán
    Ẹni o l'ẹnu, niṣe lẹ fún l′ẹnu k'ofi s′ọrọ
    Ẹni o létí, ẹ fún létí k'ofi gbọ́ràn
    Ẹni o l′órí rò, ńṣe lẹ yá l'ọpọlọ
    pre-chorus
    T'ọmọdé, t′àgbàlagbà lọ w′ojú réré rẹ
    Ukwu-ukwu, ku, wọn w'oju rere rẹ
    Ẹni tó l′owo àt'ẹni o ní, wọ́n w′ojú réré rẹ
    Kos'òun t′ole ṣe, kos'òun tó pọ'ju fún o láti ṣe

    Ìwo ṣa l′Ọba, kos′Ọba mí ràn lẹ'yìn rẹ, lẹ′yìn rẹ o
    Kos'ẹlòmíràn, Bàbá bless me, yeah-oh (níbo l′ójú rẹ wà o? Eh)
    Bàbá, jọwọ, bless me (eh, ah-ah)
    Olú Ọ̀run, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
    À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
    Olú Ọrun, yeah, níbo l′ójú rẹ wà? Ayy o
    À fẹ reeti rẹ o
    Olu Ọ'run, níbo l'ójú rẹ wà? Ayy-ayy, ayy
    À fẹ reeti rẹ oh, Bàbá
    Olú ọrùn, yeah, níbo l′ójú rẹ wà? Ayy o
    À fẹ reeti rẹ o

    Daddy, with You-′ou-'ou
    Nothing is impossible (ehn-ehn)
    Daddy, You are powerful (oh-oh, ehn, ehn o)
    Nothing wey You no fit do
    Ah-ayy, ayy o, ay, oh

    Writer(s): Barry Jhay.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Bless Me

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!