"Showa." - Kizz Daniel
(Zed)
Ahn-ahn
Alákọri, alakọkọ, ṣ′ómá fẹ mí? Ṣ'ómá là tán?
Tí ń bà gbé wá (whoo), ṣ′ómá ká kọ?
Ṣé mo máa ní problem pẹlú boys?
Ta bà já, ká padà, má sá lọ Canada
If I travel today, kí ń má bà ẹ l'ababa (l'ababa)
Army man na my army man
Army man na my brother man
Ó lè ní problem
Ahh, baby, ṣ′ówa pá oh? (Ṣ′ówá pá?)
Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lo máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin poppin', baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu rarurábà
(Ṣ′owá?)
Ṣ'òní capital business? (Ṣ′owá?)
Ṣ'òní character deaconess? (Ṣ′owá?)
Can you wake up around 4:30 (ṣ'owá?)
To make breakfast for me? (Ṣ'owá?)
Tó bà dálẹ, ṣ′olè gimme-gimme? (Ṣ′owá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ'owá?)
Gimme-gimme, k′oma gbọn mi jigi (ṣ'owá?)
Oh-ooh-oh
Long time ago, I say no kele fit make me conform, ooh-yah
Ò ká mí mọ corner (ṣ′ó)
Now, I won do am, now, I won run am (oya, uh)
Very gentle girl (whoo)
I'll pick you up, turn you biggie girl (biggie girl)
Mama say, "I don fall in love"
And my papa say, "Ọmọ, jẹun lọ"
Ahh, baby, ṣ′ówa pá oh? (Ṣ'ówá pá?)
Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lo máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin popping, baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu, rarurábà
(Ṣ'owá?)
Ṣ′òní capital business? (Ṣ′owá?)
Ṣ'òní character deaconess? (Ṣ′owá?)
Can you wake up around 4:30 (ṣ'owá?)
To make breakfast for me? (Ṣ′owá?)
Tó bà dálẹ, ṣ'olè gimme-gimme? (Ṣ′owá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ'owá?)
Gimme-gimme, k'oma gbọn mi jigi (ṣ′owá?)
Oh-ooh-oh
(Ṣ′owá?)
(Ṣ'owá?)
(Ṣ′owá?)
(Ṣ'owá?) Oh-ooh-oh
(Ṣ′owá?)
(Ṣ'owá?)
(Ṣ′owá?)
(Ṣ'owá?) Oh-ooh-oh
Writer(s): Kizz Daniel.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Showa