Barry Jhay – Wonder Lyrics

Barry Jhay – Wonder Lyrics
Wonder
Barry Jhay
    Lyrics copied!
    Wonder Album Art
    "Wonder." - Barry Jhay

    Album: Barry Back 2
    Track No: 04

    (Yo-)
    Yeah

    Take it or not, I′m blessed
    Ṣẹ gbọ o? Oh, yes
    And no son of man can take my joy away
    Wetin be my own no go pass me by
    Ẹkùn ati òṣì, bye-bye
    Tẹ ba ro pe ẹ n ṣe mi Atanda
    Ara yin lẹ n ṣe

    Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
    The horror mọ wọn lọwọ
    K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?"
    Ni mo fi sun ṣòkòtò
    Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ
    And e no get where e touch (aje, aje)
    Ladugbo yin emi l′ọn gbọ
    Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
    Kiamọsa ni ko tete
    Ma tori mi lọ jẹ gbese
    Anoti, anoti, allele
    Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
    Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè
    Psycho pọ lode

    Àwọn le mọ le ṣe
    Ẹni to mon eniyan lo n ṣ′ese eniyan o
    Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila
    Ara rẹ loo pa
    Itakun to ni kerin ma wọ′dò, to ni kerin ma wọ'dò
    Toun terin ni wọn jọ lọ (ayan o)

    Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
    The horror mọ wọn lọwọ
    K′ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?"
    Ni mo fi sun ṣòkòtò
    Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ
    And e no get where e touch (aje, aje)
    Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
    Orin wa l′ọn n jẹ nigboro
    Kiamọsa ni ko tete
    Ma tori mi lọ jẹ gbese
    Anoti, anoti, allele
    Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
    Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè
    Psycho pọ lode
    Àwọn le mọ le ṣe
    Ẹni to mon eniyan lo n ṣ′ese eniyan o

    Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila
    Ara rẹ loo pa
    Itakun to ni kerin ma wọ'dò, o ni kerin ma wọ'dò
    Toun terin ni wọn jọ lọ (Yo Dips)

    Writer(s): Olawale Adibe, Balogun Oluwakayode.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Wonder

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!